
GBOLOHUN KEEKEE
Authored by Oguntoye Bunmi
World Languages
3rd Grade
Used 11+ times

AI Actions
Add similar questions
Adjust reading levels
Convert to real-world scenario
Translate activity
More...
Content View
Student View
11 questions
Show all answers
1.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 1 pt
put the cup on the table tumo si ______
fi iwe sori tabili
fi aso sori tabili
gbe ounje sori tabili
fi ife imumi sori tabili
2.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 1 pt
Nibo ni aja yii wa?
Aja wa ni abe aga
Segun wa ni abe apoti
Aja n sunkun ni abe aga
A n sere ni abe aga
3.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 1 pt
My dad has gone to work tumo si _____
baba mi wa ninu yara won
baba mi ti sun si ibi ise
baba mi ti lo si ibi ise
baba mi ti jade
4.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 1 pt
how do you say 'my mom is cooking rice'?
mama mi ati iresi
mama mi n je iresi
mama mi feran iresi
mama mi n se iresi
5.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 1 pt
Your bag is on the chair tumo si_____
baagi re dara
baagi re wa lori aga
baagi re wa ni abe aga
mo fi baagi re si ori aga
6.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 1 pt
She is reading a book tumo si _____
o n ka iwe
o n se iwe
o n wo iwe
o n fi iwe han
7.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 1 pt
Where is the school located?
ile-iwe wa ni ibikan?
ile-iwe wa ni isale?
nibo ni ile-iwe wa?
ile-iwe wa ni oke?
Access all questions and much more by creating a free account
Create resources
Host any resource
Get auto-graded reports

Continue with Google

Continue with Email

Continue with Classlink

Continue with Clever
or continue with

Microsoft
%20(1).png)
Apple
Others
Already have an account?